Jeremiah 50:41 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Wò ó! Àwọn kan ń bọ̀ láti ìhà àríwá, orílẹ̀-èdè ńlá, ati ọpọlọpọ ọba, wọ́n ń gbára wọn jọ láti máa bọ̀ láti òkèèrè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò o, orilẹ-ède kan yio wá lati ariwa, ati orilẹ-ède nla, ọba pupọ li o si dide lati opin ilẹ aiye wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wò ó! Ọ̀wọ́ ọmọ ogun láti ìhà àríwá; orílẹ̀ èdè ńlá àti àwọn Ọba pípọ̀ ni à ń gbé dìde láti òpin ilẹ̀ ayé.