Jeremiah 50:46 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ariwo wíwó odi Babiloni yóo mi ilẹ̀ tìtì, a óo sì gbọ́ ìró rẹ̀ káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ohùn igbe nla pe: a kó Babeli, ilẹ-aiye mì, a si gbọ́ ariwo na lãrin awọn orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní dídún fèrè Bábílónì gbogbo ilẹ̀ ayé yóò mì tìtì igbe rẹ̀ yóò sì búja gbogbo àwọn orílẹ̀ èdè.