Jeremiah 50:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí wọn rí wọn ń pa wọ́n jẹ, àwọn ọ̀tá wọn sì ń wí pé, ‘A kò ní ẹ̀bi kankan, nítorí pé wọ́n ti ṣẹ OLÚWA, tí ó jẹ́ ibùgbé òdodo wọn, ati ìrètí àwọn baba wọn.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ti o ri wọn, ti pa wọn jẹ: awọn ọta wọn si wipe, Awa kò jẹbi, nitoripe nwọn ti ṣẹ̀ si Oluwa ibugbe ododo, ati ireti awọn baba wọn, ani Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn tí ó rí wọn, ti pa wọ́n jẹ àwọn ọ̀ta wọ́n sì wí pé, ‘Àwa kò jẹ̀bi nítorí pé wọ́n ti sẹ̀ sí OLÚWA ibùgbé òdodo àti ìrètí àwọn baba wọn.’