Jeremiah 51:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbé àsíá kan sókè, ẹ gbé e ti odi Babiloni; ẹ ṣe ìsénà tí ó lágbára. Ẹ fi àwọn aṣọ́nà sí ipò wọn; ẹ dira fún àwọn kan, kí wọn sápamọ́, nítorí OLUWA ti pinnu, ó sì ti ṣe ohun tí ó sọ nípa àwọn ará Babiloni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbé asia soke lori odi Babeli, mu awọn iṣọ lagbara, mu awọn oluṣọ duro, ẹ yàn ẹ̀bu: nitori Oluwa gbero, o si ṣe eyi ti o wi si awọn olugbe Babeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbé àsìá sókè sí odi Bábílónì! Ẹ ṣe àwọn ọmọ ogun gírí, ẹ pín àwọn olùsọ́ káàkiri, ẹ ṣètò àwọn tí yóò sápamọ́ OLÚWA! Yóò gbé ète rẹ̀ jáde, òfin rẹ̀ sí àwọn ará Bábílónì.