Jeremiah 51:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA àwọn ọmọ ogun ti fi ara rẹ̀ búra, pé òun yóo mú kí àwọn eniyan kún inú rẹ bí eṣú, wọn yóo sì kígbe ìṣẹ́gun lé ọ lórí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa awọn ọmọ-ogun ti fi ẹmi rẹ̀ bura pe, ni kikún emi o fi enia kún ọ gẹgẹ bi ẹlẹnga; nwọn o si pa ariwo ogun lori rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ti búra fún ara rẹ̀, Èmi yóò fún ọ ní ènìyàn gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ eṣú, wọn yóò yọ ayọ̀, iṣẹ́gun lórí rẹ.