Jeremiah 51:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òmùgọ̀ ni gbogbo eniyan, wọn kò sì ní ìmọ̀, gbogbo alágbẹ̀dẹ wúrà sì gba ìtìjú lórí oriṣa tí wọn dà; nítorí pé irọ́ ni ère tí wọ́n rọ, wọn kò ní èémí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aṣiwere ni gbogbo enia, nitori oye kò si; oju tì gbogbo alagbẹdẹ nitori ere, nitori ere didà rẹ̀ eke ni, kò si sí ẹmi ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Olúkúlùkù ènìyàn ni kò lọ́pọlọ tí kò sì ní ìmọ̀, olúkùlúkù alágbẹ̀dẹ ni a kó ìtìjú bá nípa òrìṣà rẹ̀. Àwọn ère rẹ jẹ́ ẹ̀tàn wọn kò ní èémí nínú.