Jeremiah 51:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun ti Jakọbu kò dàbí àwọn wọnyi, nítorí pé òun ní ẹlẹ́dàá ohun gbogbo; ẹ̀yà Israẹli ni eniyan tirẹ̀, OLUWA àwọn ọmọ ogun sì ni orúkọ rẹ̀. OLUWA sọ fún Babiloni pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ipin Jakobu kò dabi wọn: nitori on ni iṣe Ẹlẹda ohun gbogbo: Israeli si ni ẹ̀ya ijogun rẹ̀: Oluwa awọn ọmọ-ogun li orukọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó jẹ́ ìpín Jákọ́bù kó rí bí ìwọ̀nyí; nítorí òun ni ó dá ohun gbogbo, àti gbogbo àwọn ẹ̀yà ajogún, OLÚWA alágbára ni orúkọ rẹ̀.