Jeremiah 51:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ìwọ ni òòlù ati ohun ìjà mi: ìwọ ni mo fi wó àwọn orílẹ̀-èdè wómúwómú, ìwọ ni mo sì fi pa àwọn ìjọba run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ni òlù mi, ohun elo-ogun: emi o fi ọ fọ awọn orilẹ-ède tũtu, emi o si fi ọ pa awọn ijọba run;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ìwọ ni kùmọ̀ ohun èlò ogun mi, ohun èlò ìjà mi, pẹ̀lú rẹ èmi ó fọ́ orílẹ̀ èdè túútúú, èmi ó bà àwọn ilé Ọba jẹ́.