Jeremiah 51:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìwọ ni mo fi pa olùṣọ́-aguntan ati agbo ẹran rẹ̀ rẹ́, ìwọ ni mo fi run àgbẹ̀ ati àwọn alágbàro rẹ̀, ìwọ ni mo fi ṣẹ́ apá àwọn gomina ati ti àwọn olórí ogun.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si fi ọ fọ oluṣọ-agutan ati agbo-ẹran rẹ̀ tũtu, emi o si fi ọ fọ àgbẹ ati àjaga-malu rẹ̀ tũtu; emi o si fi ọ fọ awọn balẹ ati awọn ijoye tũtu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú rẹ, mo pa olùsọ́ àgùntàn àti agbo àgùntàn rẹ̀; pẹ̀lú rẹ, mo pa àgbẹ̀ àti màlúù, Pẹ̀lú rẹ, mo pa gómìnà àti àwọn alákòóṣo ìjọba rẹ̀.