Jeremiah 51:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí àwọn orílẹ̀-èdè múra láti gbógun tì í, kí àwọn ọba ilẹ̀ Media múra, pẹlu àwọn gomina wọn, ati àwọn ẹmẹ̀wà wọn, ati gbogbo ilẹ̀ tí ó wà lábẹ́ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sọ awọn orilẹ-ède pẹlu awọn ọba Media di mimọ́ sori rẹ̀, awọn balẹ rẹ̀, ati gbogbo awọn ijoye rẹ̀, ati gbogbo ilẹ ijọba rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pèsè àwọn orílẹ̀ èdè láti bá jagun, àwọn Ọba Médíà, Gómìnà àti gbogbo ọmọ ìgbìmọ̀ wọn àti gbogbo orílẹ̀ èdè tí wọ́n jọba lé lórí.