Jeremiah 51:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí tafàtafà má kẹ́ ọrun rẹ̀, kí ó má sì gbé ẹ̀wù irin rẹ̀ wọ̀. Má ṣe dá àwọn ọdọmọkunrin rẹ̀ sí, pa gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ run patapata.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki tafatafa fà ọrun rẹ̀ si ẹniti nfà ọrun, ati si ẹniti o nṣogo ninu ẹ̀wu irin rẹ̀: ẹ má si ṣe dá awọn ọdọmọdekunrin rẹ̀ si, ẹ run gbogbo ogun rẹ̀ patapata.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe jẹ́ kí tafàtafà yọ ọfà rẹ̀ jáde tàbí kí o di ìhámọ́ra rẹ̀; má ṣe dá àwọn ọdọ́mọkùnrin sí, pátapáta ni kí o pa àwọn ọmọ ogun rẹ̀.