Jeremiah 51:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ti gba ibi ìsọdá odò, wọ́n ti dáná sun àwọn ibi ààbò, ìbẹ̀rùbojo sì ti mú àwọn ọmọ ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati pe, a gbà awọn asọda wọnni, nwọn si ti fi ifefe joná, ẹ̀ru si ba awọn ọkunrin ogun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Odò tí ó ṣàn kọjá kò ṣàn mọ́ ilẹ̀ àbàtà gbiná, àwọn jagunjagun sì wárìrì.”