Jeremiah 51:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ kí àwọn tí ń gbé Sioni wí pé, ‘Kí ibi tí àwọn ará Babiloni ṣe sí wa ati sí àwọn arakunrin wa dà lé wọn lórí.’ Kí àwọn ará Jerusalẹmu sì wí pé, ‘Ẹ̀jẹ̀ wa ń bẹ lórí àwọn ará ilẹ̀ Kalidea.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ìwa-ika ti a hù si mi ati ẹran-ara mi ki o wá sori Babeli, bẹ̃ni iwọ olugbe Sioni yio wi; ati ẹ̀jẹ mi lori awọn olugbe, ara Kaldea, bẹ̃ni iwọ, Jerusalemu, yio wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí gbogbo ìparun tí ó ṣe sí ẹran ara wa wà lórí Bábílónì;” èyí tí àwọn ibùgbé Síónì wí. “Kí ẹ̀jẹ̀ wa wà lórí gbogbo àwọn tí ń gbé Bábílónì,” ni Jérúsálẹ́mù wí.