Jeremiah 51:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí wọ́n ṣubú, kí wọ́n sì kú ní ilẹ̀ Kalidea, kí wọ́n gún wọn ní àgúnyọ láàrin ìgboro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a pa yio si ṣubu ni ilẹ awọn ara Kaldea, awọn ti a gun li ọ̀kọ, yio si ṣubu ni ita rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo wọn ni yóò ṣubú ní Bábílónì tí wọn yóò sì farapa yánna yànna ní òpópónà.