Jeremiah 51:43 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ìlú rẹ̀ ti di àríbẹ̀rù, wọ́n ti di ilẹ̀ gbígbẹ ati aṣálẹ̀, ilẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò gbé mọ́, tí ọmọ eniyan kò sì gbà kọjá mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilu rẹ̀ ni ahoro, ilẹ gbigbe, ati aginju: ilẹ ninu eyiti ẹnikẹni kò gbe, bẹ̃ni ọmọ enia kò kọja nibẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìlú rẹ̀ yóò di ahoro, ilẹ̀ tí ó gbẹ, ilẹ tí ènìyàn kò gbé tí ènìyàn kò sì rin ìrìnàjò.