Jeremiah 51:49 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí àwọn tí ogun Babiloni pa ní àwọn orílẹ̀-èdè ayé, ti ṣubú níwájú rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni Babiloni náà gbọdọ̀ ṣubú, nítorí àwọn tí wọ́n pa ní Israẹli.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi Babeli ti mu ki awọn olupa Israeli ṣubu, bẹ̃ gẹgẹ li awọn olupa gbogbo ilẹ aiye yio ṣubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Gẹ́gẹ́ bí Bábílónì ti mú kí àwọn olùpa Ísírẹ́lì ṣubú bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ní àwọn olùpa gbogbo ilẹ̀ ayé yóò ṣubú.