Jeremiah 51:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ati Juda kò kọ̀ wọ́n sílẹ̀; ṣugbọn ilẹ̀ Kalidea kún fún ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀, tí wọ́n dá sí Ẹni Mímọ́ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Israeli ati Juda, kì iṣe opó niwaju Ọlọrun wọn, niwaju Oluwa, awọn ọmọ-ogun; nitori ilẹ wọn (Babeli) ti kún fun ẹbi si Ẹni-Mimọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé Júdà àti Ísírẹ́lì ni Ọlọ́run wọn tí í se OLÚWA alágbára kò gbàgbọ́ bí o tilẹ̀ jẹ́ pé ilé wọn kún fún kìki ẹ̀bi níwájú ẹni mímọ́ Ísírẹ́lì.