Jeremiah 51:55 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí OLUWA ń wó Babiloni lulẹ̀, ó sì ń pa á lẹ́nu mọ́. Igbe wọn ta sókè bíi híhó omi òkun ńlá
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe Oluwa ti ṣe Babeli ni ijẹ, o si ti pa ohùn nla run kuro ninu rẹ̀; riru wọn si nho bi omi pupọ, a gbọ́ ariwo ohùn wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé OLÚWA ti ṣe Bábílónì ní ìjẹ, ó sì ti pa ohun ńlá run kúrò nínú rẹ̀; rírú wọn sì ń hó bi púpọ̀, a gbọ́ ariwo ohùn wọn.