Jeremiah 51:62 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí ó sọ pé, “OLUWA, o ti sọ pé o óo pa ibí yìí run, tóbẹ́ẹ̀ tí kò fi ní sí nǹkankan tí yóo máa gbé inú rẹ̀ mọ́, ìbáà ṣe eniyan tabi ẹranko. O ní títí lae ni yóo di ahoro.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki iwọ ki o si wipe, Oluwa, iwọ ti sọ̀rọ si ibi yi, lati ke e kuro, ki ẹnikẹni má ṣe gbe inu rẹ̀, ati enia ati ẹran, nitori pe yio di ahoro lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ìwọ kí ó sì wí pé, ‘OLÚWA ìwọ ti sọ̀rọ̀ sí ibí yí, láti ké e kúrò, kí ẹnikẹ́ni má ṣe gbé inú rẹ̀, àti ènìyàn àti ẹran, nítorí pé yóò di ahoro láéláé.’