Jeremiah 51:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ife wúrà ni Babiloni jẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, ó ń pa gbogbo ayé bí ọtí; àwọn orílẹ̀-èdè mu ninu ọtí rẹ̀, wọ́n sì ń ta gbọ̀n-ọ́n-gbọ̀n-ọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Babeli jẹ ago wura lọwọ Oluwa, ti o mu gbogbo ilẹ aiye yo bi ọ̀muti: awọn orilẹ-ède ti mu ninu ọti-waini rẹ̀; nitorina ni awọn orilẹ-ède nṣogo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ifẹ́ wúrà ni Bábílónì ní ọwọ́ OLÚWA; ó sọ gbogbo ayé di ọ̀mùtí. Gbogbo orílẹ̀ èdè mu ọtí rẹ̀, wọ́n sì ti ya òmùgọ̀ kalẹ̀.