Jeremiah 52:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó bá a sọ ọ̀rọ̀ rere, ó sì fi sí ipò tí ó ga jùlọ, àní ipò tí ó ga ju ti gbogbo àwọn ọba tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ ní Babiloni lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si sọ̀rọ rere fun u, o si gbe itẹ rẹ̀ ga jù itẹ awọn ọba ti o wà pẹlu rẹ̀ ni Babeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó ń sọ̀rọ̀ rere sí i, ó sì fún un ní ìjókòó ìgbéga, èyí tí ó ju ti àwọn Ọba yóòkù lọ tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀ ní Bábílónì.