bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Jeremiah 52:5
Jeremiah 52:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n dóti ìlú náà títí di ọdún kọkanla ìjọba Sedekaya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A si há ilu na mọ titi di ọdun ikọkanla Sedekiah ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìlú náà sì wá lábẹ́ ìhámọ́ títí di ọdún kọkànlá Ọba Sédékáyà.