Jeremiah 6:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Nítorí náà, ẹ gbọ́, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè, kí ẹ̀yin eniyan sì mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina, gbọ́, ẹnyin orilẹ-ède, ki ẹ si mọ̀, ẹnyin ijọ enia, ohun ti o wà ninu wọn!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, gbọ́ ẹ̀yin orílẹ̀-èdè kíyèsí, kí ẹ sì jẹ́ ẹlẹ́rìí ohun tí yóò sẹlẹ̀ sí wọn.