Jeremiah 6:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, “Wò ó, àwọn eniyan kan ń bọ̀ láti ilẹ̀ àríwá, orílẹ̀-èdè ńlá ń gbéra bọ̀ láti òpin ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa wi, sa wò o, enia kan ti ilu ariwa wá, ati orilẹ-ède nla kan yio ti opin ilẹ aiye dide wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni OLÚWA wí: “Wò ó, àwọn ọmọ-ogun ń bọ̀ wá láti ilẹ̀ àríwá, a ó sì gbé orílẹ̀-èdè ńlá dìde láti òpin ayé wá.