Jeremiah 6:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ má lọ sinu oko, ẹ má sì ṣe rìn lójú ọ̀nà náà, nítorí ọ̀tá mú idà lọ́wọ́, ìdágìrì sì wà káàkiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Máṣe lọ si inu oko, bẹ̃ni ki o má si rin oju ọ̀na na, nitori idà ọ̀ta, idagiri wà yikakiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Má ṣe jáde lọ sí orí i pápá tàbí kí o máa rìn ní àwọn ojú ọ̀nà, nítorí ọ̀tá náà ní idà, ìpayà sì wà níbi gbogbo.