Jeremiah 6:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọba ati àwọn ọmọ ogun wọn yóo kọlù ú, wọn yóo pa àgọ́ yí i ká, ẹgbẹ́ ọmọ ogun kọ̀ọ̀kan yóo pàgọ́ sí ibi tí ó wù ú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn oluṣọ-agutan pẹlu agbo wọn yio tọ̀ ọ wá, nwọn o pa agọ wọn yi i ka olukuluku yio ma jẹ ni àgbegbe rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Olùṣọ́ àgùntàn pẹ̀lú agbo wọn yóò gbógun tì wọ́n. Wọn yóò pa àgọ́ yí wọn ká, olúkúlùkù yóò máa jẹ ní ilé rẹ̀.”