Jeremiah 6:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọn yóo sì wí pé, “Ẹ múra kí á bá a jagun; ẹ dìde kí á lè kọlù ú lọ́sàn-án gangan!” Wọn óo tún sọ pé, “A gbé! Nítorí pé ọjọ́ ti lọ, ilẹ̀ sì ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣú!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ ya ara nyin si mimọ́ lati ba a jagun; dide, ki ẹ si jẹ ki a goke li ọsan. Egbe ni fun wa! nitori ọjọ nlọ, nitori ojiji ọjọ alẹ nà jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Múra sílẹ̀ láti bá a jagun! Dìde, kí a kọ lù ú ní ìgbà ọ̀sán! Àmọ́ ó ṣe, nítorí ọjọ́ lọ tán, ọjọ́ alẹ́ náà sì gùn sí i.