Jeremiah 6:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ dìde kí á lè kọlù ú, lóru; kí á wó àwọn ilé ìṣọ́ rẹ̀ lulẹ̀!”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dide, ẹ jẹ ki a goke lọ li oru, ki a si pa ãfin rẹ̀ run.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a kọ lù ú ní àṣálẹ́ kí a sì ba odi alágbára rẹ̀ jẹ́.”