Jeremiah 7:29 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ẹ gé irun orí yín dànù, ẹ lọ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn lórí òkè, nítorí OLUWA ti kọ ìran yín sílẹ̀, ó ti fi ibinu ta ìran yín nù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fá irun ori rẹ, ki o si sọ ọ nù, ki o si sọkun lori oke: nitori Oluwa ti kọ̀ iran ibinu rẹ̀ silẹ, o si ṣa wọn tì.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ṣe irun yín kí ẹ sì dàanù, pohùnréré ẹkún lorí òkè aṣálẹ̀, nítorí OLÚWA ti kọ ìran yìí tí ó wà lábẹ́ ìbínú rẹ̀ sílẹ̀.