Jeremiah 8:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbọ́ bí ẹṣin wọn tí ń fọn imú, ní ilẹ̀ Dani; gbogbo ilẹ̀ ń mì tìtì nítorí ìró yíyan ẹṣin wọn. Wọ́n wá run ilẹ̀ náà, ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀, ati ìlú ati àwọn tí wọn ń gbé inú rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati Dani ni a gbọ́ fifọn imu ẹṣin rẹ̀; gbogbo ilẹ warìri fun iro yiyan akọ-ẹṣin rẹ̀; nwọn si de, nwọn si jẹ ile run, ati eyi ti mbẹ ninu rẹ̀: ilu ati awọn ti ngbe inu rẹ̀,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìró ìfọnmú ẹsin àwọn ọlọ̀tẹ̀ là ń gbọ́ láti Dánì yíyan àwọn akọ ẹsin mú gbogbo ilẹ̀ wárìrì. Wọ́n wá láti pa ilẹ̀ náà run, gbogbo ohun tó wà níbẹ̀, ìlú náà àti gbogbo olùgbé ibẹ̀.”

Recommended Reading