Jeremiah 8:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ọgbẹ́ àwọn eniyan mi ni ọkàn mi ṣe gbọgbẹ́. Mò ń ṣọ̀fọ̀, ìdààmú sì bá mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ipalara ọmọbinrin enia mi li a ṣe pa mi lara; emi ṣọ̀fọ, iyanu si di mi mu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Níwọ̀n ìgbà tí a pa àwọn ènìyàn mi run, èmi náà run pẹ̀lú, mo sọ̀fọ, ìrora sì mú mi káká.