Jeremiah 9:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Orí mi ìbá jẹ́ kìkì omi, kí ojú mi sì jẹ́ orísun omijé; tọ̀sán-tòru ni ǹ bá fi máa sọkún, nítorí àwọn eniyan mi tí ogun ti pa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ORI mi iba jẹ omi, ati oju mi iba jẹ orisun omije, ki emi le sọkun lọsan ati loru fun awọn ti a pa ninu ọmọbinrin enia mi!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Áà! Orí ìbá jẹ́ orísun omi kí ojú mi sì jẹ́ orísun omijé Èmi yóò sì sunkún tọ̀sán tòru nítorí pípa àwọn ènìyàn mi.