Jeremiah 9:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí a gbọ́ tí ẹkún sọ ní Sioni, wọ́n ń ké pé, ‘A gbé! Ìtìjú ńlá dé bá wa, a níláti kó jáde nílé, nítorí pé àwọn ọ̀tá ti wó ilé wa.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori a gbọ́ ohùn ẹkun lati Sioni, pe, A ti pa wa run to! awa dãmu jọjọ, nitoriti a kọ̀ ilẹ yi silẹ, nitoriti ibugbe wa tì wa jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A gbọ́ igbe ìpohùnréré ẹkún ní Síónì: ‘Àwa ti ṣègbé tó! A gbọdọ̀ fi ilẹ̀ wa sílẹ̀, nítorí pé àwọn ilé wa ti parun.’ ”