Jeremiah 9:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ikú ti dé ojú fèrèsé wa, ó ti wọ ààfin wa. Ikú ń pa àwọn ọmọde nígboro, ati àwọn ọdọmọkunrin ní gbàgede.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iku ti de oju ferese wa, o ti wọ̀ inu ãfin wa, lati ke awọn ọmọ-ọmu kuro ni ita, ati awọn ọmọdekunrin kuro ni igboro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ikú ti gba ojú fèrèsé wa wọlé ó sì ti wọ odi alágbára wa ó ti ké àwọn ọmọ kúrò ní àdúgbò àti àwọn ọ̀dọ́mọ́kùnrin kúrò ní gbọ̀ngàn ìta gbangba.