Jeremiah 9:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ahọ́n wọn dàbí ọfà apanirun, wọ́n ń sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn. Olukuluku ń sọ̀rọ̀ alaafia jáde lẹ́nu fún aládùúgbò rẹ̀, ṣugbọn ète ikú ni ó ń pa sí i ninu ọkàn rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ahọn wọn dabi ọfa ti a ta, o nsọ ẹ̀tan, ẹnikini nfi ẹnu rẹ̀ sọ alafia fun ẹnikeji rẹ̀, ṣugbọn li ọkàn rẹ̀ o ba dè e.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ahọ́n wọn dàbí ọfà olóró ó ń sọ ẹ̀tàn; oníkálukú sì ń fi ẹnu rẹ̀ sọ̀rọ̀ àlàáfíà sí aládúgbò rẹ̀; ní inú ọkàn rẹ̀, ó dẹ tàkúté sílẹ̀.