Job 10:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ayé sú mi, nítorí náà n kò ní dákẹ́ ìráhùn; n óo sọ̀rọ̀ pẹlu ìbànújẹ́ ọkàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AGARA ìwa aiye mi da mi tan, emi o tú aroye mi sode lọdọ mi, emi o ma sọ ninu kikorò ibinujẹ ọkàn mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Agara ìwà ayé mi dá mi tán, èmi yóò tú àròyé mi sókè lọ́dọ̀ mi, èmi yóò máa sọ níní kíkorò ìbìnújẹ́ ọkàn mi.