Job 10:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí mo bá ṣe àìdára, mo gbé, ṣugbọn bí mo ṣe dáradára, n kò lè yangàn, nítorí ìbànújẹ́ ati ìtìjú bò mí mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi mo ba ṣe ẹni-buburu, egbé ni fun mi! bi mo ba si ṣe ẹni-rere, bẹ̃li emi kò si le igbe ori mi soke. Emi damu, mo si wo ipọnju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí mo bá ṣe ẹni búburú, ègbé ni fún mi! Bí mo bá sì ṣe ẹni rere, bẹ́ẹ̀ ni èmi kò sì le gbe orí mi sókè. Nítorí mo wà nínú ìtọ́jú púpọ̀, mo sì wo ìpọ́jú mi.