Job 10:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O wá àwọn ẹlẹ́rìí tuntun pé kí wọ́n dojú kọ mí, O tún bẹ̀rẹ̀ sí bínú sí mi lọpọlọpọ, O mú kí ogun mìíràn dó tì mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ si tun sọ awọn ẹlẹri rẹ si mi di ọtun, iwọ si sọ irunu rẹ di pipọ si mi, ayipada ati ogun dó tì mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ sì tún sọ àwọn ẹlẹ́rìí rẹ sí mi di ọ̀tún, Ìwọ sì sọ ìrúnú rẹ di púpọ̀ sí mi; Àyípadà àti ogun dó tì mí.