Job 11:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó di ìgbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ bá bí ọmọ rẹ̀ ní eniyan, kí òmùgọ̀ eniyan tó gbọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Enia lasan a sa ma fẹ iṣe ọlọgbọ́n, bi a tilẹ ti bi enia bi ọmọ kẹtẹkẹtẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n òmùgọ̀ ènìyàn yóò di ọlọgbọ́n, nígbà tí ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ bá bí ènìyàn.