Job 11:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kì bá jẹ́ fi àṣírí ọgbọ́n hàn ọ́, nítorí ìmọ̀ rẹ̀ pọ̀ lọpọlọpọ. Mọ̀ dájú pé ìyà tí Ọlọrun fi jẹ ọ́ kò to nǹkan lẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o si fi aṣiri ọgbọ́n hàn ọ pe, o pọ̀ jù oye enia lọ; nitorina mọ̀ pe: Ọlọrun kò bere to bi ẹbi rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ó sì fi àsírí ọgbọ́n hàn ọ́ pé, ó pọ̀ ju òye ènìyàn lọ; Nítorí náà, mọ̀ pé Ọlọ́run ti gbàgbé àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kan.