Job 12:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òun níí sọ àwọn orílẹ̀-èdè di ńlá, òun náà níí sìí tún pa wọ́n run: Òun níí kó àwọn orílẹ̀-èdè jọ, òun náà níí sì ń tú wọn ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On a mu orilẹ-ède bi si i, a si run wọn, on a sọ orilẹ-ède di nla, a si tun ṣẹ́ wọn kù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun a mú orílẹ̀-èdè bí sí i, a sì run wọ́n; Òun a sọ orílẹ̀-èdè di ńlá, a sì tún ṣẹ̀ wọn kù.