Job 12:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó gba ìmọ̀ kúrò lọ́wọ́ àwọn ìjòyè ní gbogbo ayé, ó sì sọ wọ́n di alárìnká ninu aṣálẹ̀, níbi tí ọ̀nà kò sí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On a gbà aiya olú awọn enia aiye, a si ma mu wọn wọ́ kakiri ninu iju nibiti ọ̀na kò si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun a gba àyà olú àwọn ènìyàn aráyé, A sì máa mú wọn wọ́ kiri nínú ijù níbi tí ọ̀nà kò sí.