Job 13:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ohun tí ẹ mọ̀ wọnyi, èmi náà mọ̀ ọ́n, ẹ kò sàn jù mí lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohun ti ẹnyin mọ̀, emi mọ̀ pẹlu, emi kì iṣe ọmọ-ẹhin nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohun tí ẹ̀yin mọ̀, èmi mọ̀ pẹ̀lú, èmi kò rẹ̀yìn sí yin.