Job 15:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n hu ewú lórí wà láàrin wa, ati àwọn àgbàlagbà, àwọn tí wọ́n dàgbà ju baba rẹ lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Elewú ogbó ati ògbologbo enia wà pẹlu wa, ti nwọn gbó jù baba rẹ lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Eléwú ogbó àti ògbólógbòó ènìyàn wà pẹ̀lú wa, tí wọ́n gbójú baba rẹ lọ.