Job 15:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
(ohun tí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n sọ, tí àwọn baba wọn kò sì fi pamọ́,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti awọn ọlọgbọ́n ti pa ni ìtan lati ọdọ awọn baba wọn wá, ti nwọn kò si fi pamọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tí àwọn ọlọ́gbọ́n ti pa ní ìtàn lati ọ̀dọ̀ àwọn baba wọn wá, ti wọ́n kò sì fi pamọ́,