Job 15:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
àwọn nìkan ni a fún ní ilẹ̀ náà, àlejò kankan kò sì sí láàrin wọn).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a fi ilẹ aiye fun nikan, alejo kan kò si là wọn kọja.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí a fi ilẹ̀ ayé fún nìkan, àlejò kan kò sì là wọ́n kọjá.