Job 15:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni ibi ń yí ninu ìrora ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀, àní, ní gbogbo ọdún tí a là sílẹ̀ fún ìkà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Enia buburu nṣe lãlã, pẹlu irora li ọjọ rẹ̀ gbogbo, ati iye ọdun li a dá silẹ fun aninilara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ènìyàn búburú ń ṣe làálàá, pẹ̀lú ìrora, ní ọjọ́ rẹ̀ gbogbo, àti iye ọdún ní a dá sílẹ̀ fún aninilára.