Job 15:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ń gbé ìlú tí ó ti di ahoro, ninu àwọn ilé tí eniyan kò gbọdọ̀ gbé, àwọn ilé tí yóo pada di òkítì àlàpà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si gbe inu ahoro ilu itakété, ati ninu ileyile ti enia kò gbe mọ́, ti o mura tan lati di àlapa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun sì gbé inú ahoro ìlú ìtakété, àti nínú iléyílé tí ènìyàn kò gbé mọ́, tí ó múra tán lati di àlàpà.