Job 15:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí asán ni àwùjọ àwọn tí wọn kò mọ Ọlọ́run, iná yóo sì jó ilé àwọn tí ń gba owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe ajọ awọn àgabagebe yio tuka, iná ni yio si jo agọ abẹtẹlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé ayọ̀ àwọn àgàbàgebè yóò túká, iná ní yóò sì jó àgọ́ àwọn tí ó fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀.