bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Job 16:14
Job 16:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ń gbógun tì mí nígbà gbogbo, ó pakuuru sí mi bí ọmọ ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibajẹ lori ibajẹ li o fi ba mi jẹ; o sure kọlù mi bi òmirán.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbàjẹ́ lórí ìbàjẹ́ ní ó fi bà mí jẹ́; ó súré kọlù mi bí jagunjagun.